Friday 24 March 2017

Aworo Itaja

Image result for ifa yoruba

EWE-AWOYOYO TUTU OOJO, 
EWE ETIPON-OLA TUTU  OOJO, 
IMI OJO, 
IYEPE OJA TI O BA MA NKUN DADA, OJU OJA LAO TI BU IYEPE NAA
OSE IYETI O BA WU WA. 
AO KOKO GUN EWE MEJEJI YEN PAPO , AO FI IMI-OJO SI, LEYIN NA NI AO DA YEPE OJA YEN SI TI AO SI GUN PAPO. TI A BA GUN TAN,AO KO SINU IGBA-FUNFUN TABI IKE-FUNFUN,AO TE NI IFA EJI-OGBE AO WA PE IFA RE SI.


12 comments:

  1. E jowo baba kini ifa ogun yi ti ao pe si,agba yin a dale o

    ReplyDelete
  2. Baba amajuyin she o'kini ifa ose yi

    ReplyDelete
  3. Baba ejo efun Mi ni noba yin

    ReplyDelete
  4. Ejo baba wa kini ifa tama pe si sir amaa juu yin se o amin.

    ReplyDelete
  5. Ewe amaje o egbo ama too olubiki ati osanyin bikin ama fun yin se ase ejowo kini ifa Ogun yi

    ReplyDelete
  6. BABA e Ku ojo meta ejowo efun mi lesi kinni mo le se lati LA laye mi

    ReplyDelete
  7. Baba yoma joyinse o kini IFA re

    ReplyDelete
  8. Baba, ewe amo je ooo
    Ejowo e fun mi ohun Ifa yi.
    Baami, Ifa Agbe yin oo, ese baba aama ju yin se

    ReplyDelete
  9. baba ejowo kini ifa ise yii. atiwipe mo nidi nomba yin

    ReplyDelete