Tuesday 28 March 2017

Oogun Majele


Image result for ogun ibile yoruba todaju

ikamudu oju ona tio to telerawon, ao fi eko elewe ko, gbogbo eyi ti o tele ra won ni oju ona ni o, ao jo pelu odidi atare kan ao sin nigbere yipo orun .ifunra loogun agba ,ti aba nifunra ao ma gbo bi awon ikamudu yi se ma hoo yuuuuunnnn,nigbati won ba fe fi ogun sinu ounje fun wa.


Ejowo e click facebook like ati Google + like ti eba like post yi.

Adupe

Friday 24 March 2017

Aworo Itaja

Image result for ifa yoruba

EWE-AWOYOYO TUTU OOJO, 
EWE ETIPON-OLA TUTU  OOJO, 
IMI OJO, 
IYEPE OJA TI O BA MA NKUN DADA, OJU OJA LAO TI BU IYEPE NAA
OSE IYETI O BA WU WA. 
AO KOKO GUN EWE MEJEJI YEN PAPO , AO FI IMI-OJO SI, LEYIN NA NI AO DA YEPE OJA YEN SI TI AO SI GUN PAPO. TI A BA GUN TAN,AO KO SINU IGBA-FUNFUN TABI IKE-FUNFUN,AO TE NI IFA EJI-OGBE AO WA PE IFA RE SI.